Àsejù
Lyrics
Emi a se iwon ti mo le se
Àsejù ni kpomolomo o
Kirakita o dola
Ti ishe eda kan le se.
Àsejù ni kpomolomo o
Emi a se iwon ti mo le se
Àsejù ni kpomolomo o
Kirakita o dola
Ti ishe eda kan le se.
Àsejù ni kpomolomo o
Everywhere I go.
(Everywhere I go)
Everything I do
(Everything I do)
Problems far away
(Blessings follow me)
Favour Follow
(Bad belle stay away from me)
(Trouble stay away from me)
I no dey jealous person work
(I no dey tire for my own)
Emi a se iwon ti mo le se
(Olaide)
Àsejù ma lo n kpomolomo o
(Kpomolomo je)
Kirakita o dola
Ti ishe eda kan le se.
Àsejù lo n kpomolomo o
Emi a se iwon ti mo le se
Àsejù ma lo n kpomolomo o
Kirakita o dola
Ti ishe eda kan le se o.
Àsejù lo n kpomolomo o
Ehh
Ehh Ehh Eh
Ehh Eh
Ehh Ahh
Oo
Oo oo o
Oh Oh
oh oh Ah
Emi a a se iwon iwon iwon iwon
Emi a a se iwon iwon iwon iwon
Se iwon die
O je sewon sewon die
O je sewon sewon die
Ani sewon sewon die
Ah
Se iwon die
O je sewon sewon die
O je sewon sewon die
O je sewon sewon die
Emi a se iwon ti mo le se
Àsejù ma lo n kpomolomo o
(Kpomolomo je)
Kirakita o dola
Ti ishe eda kan le se.
Àsejù lo n kpomolomo o
(Kpomolomo je)
T.Ollyvar Eh
Writer(s): Temitope Adewale
Copyright(s): Lyrics © T.Ollyvar
Lyrics Licensed & Provided by LyricFind
The Meaning of Àsejù
Be the first!
Post your thoughts on the meaning of "Àsejù".