Awé
Awé

Asa - Awé Lyrics

Pop
Feb 17, 2008
480
Awé Music Video

Awé Lyrics

Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo

Anti to n gbe le I to si
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo

O wi kpe o, o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
Oloyun fun o

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Anti ton loyun fun o
O to bi e l'omo
I wo iwo na

Anti to loyun fun o
O to bi e l'omo, o bi 'mo oh oh
O bi 'mo Ire lo ni mu, ese
Irun ori,iwo dudu
Omo kpu pa ba wo lo se ri

Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed

Ewa wo ja la a fin
Oba ejigbo atabo, atako
Wan ja la fin oba La fin oba.

Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le,mabo loko mabo l'eko

Mama to bi mama re
Ni mama mi, emi na bi te mi
Moo ntomo lowo f'omo loyon
Ma ko tire bami

Abo oro lan so f'omo Luabi
To ba de nu re a do n di n di
Din din

Writer(s): BUKOLA ELEMIDE, COBHAMS EMMANUEL ASUQUO
Copyright(s): Lyrics © Sony/ATV Music Publishing LLC
Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Attach an image to this thought

Drag image here or click to upload image

The Meaning of Awé

Be the first!

Post your thoughts on the meaning of "Awé".

Latest Blog Posts
Lyrics Discussions

1

800

1

7

1

134
Hot Songs

1

2K
Recent Blog Posts