Possible
Possible

9ice - Possible Lyrics

3

Possible Lyrics

Yeaaah
Palasa o fa yu dika
So bu ka fa kaari do

He made the impossibility possible
He made the impossibility possible
Oun gbe inu mi baba
Oun gbe ninu mi omo
Oun gbe ninu mi emi mimo ooo

Sa dede ni mo ji mo ba ila latewo mi
Mi o mo eni to ko ayan mo lo fi ye mi
Ahh baba wo ni ko sese
Wo ni baayi ni ma ba ku
Baba wa damilare baba ma je kin jeebi
Baba ma fi oju mi rare
Baba ma jen je je yi yiiiiii

He made the impossibility possible
He made the impossibility possible
Oun gbe inu mi baba
Oun gbe ninu mi omo
Oun gbe ninu mi emi mimo ooo

Arun tio gba ogun oluwa ma fi kan mi
Arun tio se wo eleda ma mu ba mi
Oun to dun mi lokan baba je ko di opin
Oun ti aye fin bu mi baba fi funmi

Iwo loni ti ba kokun a si
Iwo loni bi nba beere wa fi fun mi
Ma je ma je o pe ju tete se
Ma je o pe ju tete se
Olorun iwo nikan lo le se
Tete se koma di gobe
Eleda ma sun

He made the impossibility possible
He made the impossibility possible
Oun gbe inu mi baba
Oun gbe ninu mi omo
Oun gbe ninu mi emi mimo ooo

In tongues

He made the impossibility possible
He made the impossibility possible
Oun gbe inu mi baba
Oun gbe ninu mi omo
Oun gbe ninu mi emi mimo ooo

Copyright(s): Lyrics © TUNECORE INC, TuneCore Inc.
Lyrics Licensed & Provided by LyricFind

Attach an image to this thought

Drag image here or click to upload image

The Meaning of Possible

Be the first!

Post your thoughts on the meaning of "Possible".

Latest Blog Posts
Lyrics Discussions
Hot Songs
Recent Blog Posts